VIEW MAIN SITESearch this site here


ORIKI OGBOMOSO


Ogbomoso omo ajilete nbi won gbe n
jeka ki won oto muko yangan ogbomoso afogbo ja bi esu odara.
Ngba ogbomoso ba se o n ti o se tan Bo logbon inu osebi ere ni omo
ajileten ba olu ware se ni. Ogun o
jaja ki o kogbomoso ri e de inu oko
esinmin Ogbomoso Ajilete si ogo re l'a fe
korin, Iwo t'a te s'arin odan, Okan
ninu ilu Akin Ibaruba niwon eledin ese, omo ode
bare eti oya Oun ni baba to se gbogbo won le
patapata porogodo Kekere asa omo ajuuju bala Agbalagba asa omo ajuuju bala Kekere ladaba subu tawon ti n je
laarin ota Oloumi kekke lo ti n soko won nile Kekere lo ti n soko won lóki Kekere lojo ti n soko won lona iju

»Comment Here
BACK FORWARD

Select Category...



Rh
MY Disclaimer
Online : 1 User(s)
Today : 1 Guests
Total : 24 Visitors

This is a Mobile Website

Created For the Awareness/Publicizing Of Educational News, Social News And Fun

This site is hosted by:
XTgem.com !!!
Owned/Controlled By Oke Oluwashina Stephen
This Site contains
  • Educational News
  • Tutorials/Funs
  • Social News
Thanks
You can try to»COMMENT HERE
My Contact:09028928927
Author:Oke Oluwashina Stephen
¤>>Thanks For Visiting!!!>>¤
This Site Is Fully Created By
OkeOluwashinaStephen

Back to the Top

Copyright © . Theme by GodsGrace TEAM
24

©2017 By Oke Oluwashina Stephen
image09030073529
All rights Reserved© 2017-2020Powered by:+OLUWASHINA
2GO ARENA
The Soda Pop